
Eyanmi,
Nje o mo wipe eyan ki gbin alubosa ko hu efo? Laelae!!! Eyan o de le gbin ako isu ko hu ewura, ohun to ba gbin ohun lo maa ka.
Ti o ba hun pa omolomo lekun Jaiye, ti o ni kosi eda kan to le mu e, ranti wipe mo nbo wa Olorun le ma je loogun odun, esan nbo wa ke ooo. Mo wi temi ooo.

Ati ri awon to je wipe oju aye ni won hun se kiri. Won a fi eje sinu won a maa tuto funfun jade. Won a maa wa ati da irin Ajo eleran ara bi tiwon ru. Nitori owu jije, ilaara, tabi ikoorira.
Awon ni won a pe ole ko wa ja, awon noni a tun pe oloko kowa mu. Gbogbo e lati gbayi loju araaye. Esan wa ooo.

-
Organic Irish Seaweed Soap€5.99
-
Ageless Facial Moisturizer€19.99
-
Product on saleSoothing Moisturiser For Dry Sensitive Skin-800gOriginal price was: €59.99.€49.99Current price is: €49.99.
-
4 Handmade Organic Turmeric Soaps€17.99
-
4 Organic Liquorice Anti-aging Soaps€19.99
-
4 AFRICAN BLACK BAR SOAPS€17.99
-
Product on saleOrganic Irish Seaweed Exfoliating SoapsOriginal price was: €24.99.€19.99Current price is: €19.99.
-
Organic Liquid African Black Soap€12.99 – €19.99
-
Organic Creamy Coffee Scrub€29.99

Elomiran a ni ohun she adura titi Olorun ko daa ohun lohun, e bawa bi leere pe ko lo ye ise Owo e wo, se Owo re mo?
Mo dupe gan fun asiko ti e fisile lati ka aroye mi. E jowo e je kin gbo ero okan yin lori oro yi ni aiye towa ni isale. E dakun e fi ife han mi, Eba mi pin aroye yin fun awon ore yin. Esi ma gbagbe lati darapo mowa ni ibiyi.
Emi ni ti e ni tooto,
Ruka
Check Natural Skincare Products here. Homemade Recipes here.